Àwọ̀ ní èdè Yorùbá

Ẹ ǹlẹ́ o,

Ẹ kúu dédé àsìkò yí. Nínú àròkó yìí a ó sọ̀rọ̀ ní ṣókí nípa àwọ̀ ní èdè Yorùbá àti ìtúmọ̀ wọn ní ède Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn nìyìí:

Funfun – white/ cream
Dúdú – black / dark colours
Pupa – red / bright colours
Ewéko – green(ish)
Ewé – green(ish)
Wúrà – golden
Fàdákà – silver
Igi – brown
Ara – brown
Búráùn – brown
Aró – blue
Búlúù – blue
Elese àlùkò – purple
Pọ́pù – purple
Pupa fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́ – pink
Òféèfé – orange
Omi ọsàn – orange
Ìyèyè – yellow
Pupa rúsúrúsú – yellow
Yẹ́lò – yellow
Eérú – ash colour/grey

Ó dàbọ̀.

An easy way to type in Yoruba on a Mac

Hi folks,

In this post I will talk about an easy way to type in Yoruba on a Mac. The little challenge with typing Yoruba properly with a standard keyboard is that it takes some effort to add diacritics, which are various dots and squiggles that appear on certain Yoruba alphabets. One solution to writing Yoruba easily is to use the Yoruba keyboard layout talked about on the Manemo Matemu website.

Once you install the layout in your Library/Keyboard Layouts folder, you can then select the layout as your keyboard input source.

Then you can type Yoruba as follows:

  • All the keys remain the same as on the regular U.S. keyboard
  • To add a dot under e, s, and o:  ALT + letter (eg ALT + o to type ọ).
  • Capital s, e or o with dot: SHIFT + ALT + letter
  • High tone (mi): ALT + h
  • Low tone (do): ALT + l

That’s all for now. Till next time, happy Yoruba writing.